Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Wọ́n Yááfì Ohun Ìní Wọn fún Jèhófà

Wọ́n Yááfì Ohun Ìní Wọn fún Jèhófà

Àwọn ìdílé kan fi ilé àti ilẹ̀ wọn sílẹ̀, wọ́n sì kó lọ sí Jerúsálẹ́mù (Ne 11:1; w98 10/15 22 ¶13)

Wọ́n súre fún àwọn tó yọ̀ǹda ara wọn láti lọ máa gbé ní Jerúsálẹ́mù (Ne 11:2; w86 6/1 21)

Ìbùkún tí Jèhófà máa ń fúnni máa ń pọ̀ ju ohunkóhun téèyàn yááfì lọ (Mal 3:10; w16.04 8 ¶15)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn ìbùkún wo ni mo ti rí nígbà tí mo yááfì àwọn nǹkan kan kí n lè ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà?’