Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Fẹ́ Yan Ọ̀rẹ́

Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Tó O Bá Fẹ́ Yan Ọ̀rẹ́

Òfin Ọlọ́run sọ pé àwọn ọmọ Ámónì àti àwọn ọmọ Móábù kò gbọ́dọ̀ “wá sínú ìjọ” torí pé wọ́n ti fìgbà kan rí ta ko àwọn èèyàn Ọlọ́run (Ne 13:1, 2; it-1 95 ¶5)

Élíáṣíbù Àlùfáà Àgbà fún ọmọ Ámónì kan láyè láti máa lo yàrá ìjẹun tó wà nínú tẹ́ńpìlì (Ne 13:4, 5; w13 8/15 4 ¶5-6)

Nehemáyà fi hàn pé òun jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà, ó sì da gbogbo ẹrù ọ̀tá Jèhófà náà síta (Ne 13:7-9)

Tá a bá yan àwọn tí kò nífẹ̀ẹ́ Jèhófà lọ́rẹ̀ẹ́, ṣé ìyẹn á fi hàn pé a jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà?​—w96 3/15 16 ¶6.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé inú Jèhófà máa dùn sí irú àwọn ọ̀rẹ́ tí mò ń bá rìn yìí?