August 7-13
NEHEMÁYÀ 5-7
Orin 17 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Nehemáyà Fi Ara Ẹ̀ Jìn Dípò Kó Jẹ Gàba”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Ne 6:13—Kí nìdí tó fi máa jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí Nehemáyà bá lọ sá pa mọ́ sínú tẹ́ńpìlì? (w07 7/1 30 ¶15)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ne 5:1-13 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 6)
Àsọyé: (5 min.) w13 5/15 7 ¶17-19—Àkòrí: Àwọn Ajíhìnrere Tó Mọṣẹ́ Máa Ń Ran Ara Wọn Lọ́wọ́. (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Wọ́n Ń Ṣiṣẹ́ Kára Nítorí Wa”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 53
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 35 àti Àdúrà