July 17-23
Ẹ́SÍRÀ 9-10
Orin 89 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Téèyàn Bá Ṣàìgbọràn, Ó Máa Jìyà Ẹ̀”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Ẹsr 10:44—Kí nìdí tí wọ́n fi lé àwọn ìyàwó tó jẹ́ àjèjì náà lọ tọmọtọmọ? (w06 1/15 20 ¶2)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹsr 9:1-9 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Fi ìwé àṣàrò kúkúrú náà Ǹjẹ́ Ìyà Lè Dópin? nasẹ̀ àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 13)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Pe ẹni náà wá sípàdé, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 11 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ àti kókó 1-3 (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ìgbọràn Máa Ń Dáàbò Bò Wá (2Tẹ 1:8): (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ló máa ṣẹlẹ̀ kí Amágẹ́dọ́nì tó bẹ̀rẹ̀?
Àǹfààní wo la máa rí tá a bá jẹ́ onígbọràn báyìí?
Báwo ni Amágẹ́dọ́nì àti ìgbọràn ṣe so kọ́ra?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 50 kókó 6-7 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 133 àti Àdúrà