Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà”

“Lójú Ẹsẹ̀, Mo Gbàdúrà”

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Nehemáyà.]

Nehemáyà gbàdúrà kó tó dáhùn ìbéèrè tí ọba bi í (Ne 2:2-4; w08 2/15 3 ¶5)

Ọba ṣe ohun tí Nehemáyà béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ (Ne 2:5, 6)

RONÚ LÓRÍ ÌBÉÈRÈ YÌÍ: Kí la lè ṣe tẹ́nì kan bá bi wá láìròtẹ́lẹ̀ pé ká ṣàlàyé ohun tá a gbà gbọ́?​—be 178 ¶4.