Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

August 12-18

SÁÀMÙ 73-74

August 12-18

Orin 36 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. Kí La Lè Ṣe Tá Ò Fi Ní Máa Jowú Àwọn Tí Ò Sin Jèhófà?

(10 min.)

Tá ò bá kíyè sára, a lè máa jowú àwọn tí ò sin Ọlọ́run (Sm 73:3-5; w20.12 19 ¶14)

Dípò ká ya ara wa sọ́tọ̀, ṣe ló yẹ ká dara pọ̀ mọ́ àwọn ará wa láti jọ́sìn Jèhófà, ìyẹn á jẹ́ ká lè ní èrò tó tọ́ (Sm 73:17; Owe 18:1; w20.12 19 ¶15-16)

“Orí ilẹ̀ tó ń yọ̀” làwọn tí ò sin Jèhófà wà, àmọ́ àwọn tó ń sin Jèhófà máa “wọnú ògo” (Sm 73:18, 19, 24; w14 4/15 4 ¶5; w13 2/15 25-26 ¶3-5)

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Sm 74:13, 14—Kí ni “Léfíátánì” ṣàpẹẹrẹ? (it-2 240)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Lo àǹfààní tó bá yọ láti sọ fún ẹnì kan tó o mọ̀ nípa ohun tó o kọ́ nípàdé láìpẹ́ yìí. (lmd ẹ̀kọ́ 2 kókó 4)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. Fi bá a ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì han ẹni náà. (lmd ẹ̀kọ́ 8 kókó 3)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(5 min.) Àsọyé. ijwbq 89—Àkòrí: Ṣé Gbogbo Ìsìn Ló Dáa? (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 72

7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ

(15 min.)

8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 98 àti Àdúrà