Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
JÍ!
Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Jí! yìí sọ̀rọ̀ nípa kókó pàtàkì kan. [Fún onílé ní ẹ̀dà kan.]
Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ o mọ̀ pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń túmọ̀ àwọn ìwé wa sí ohun tó ju ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó lé àádọ́ta [750] èdè lọ?
Ka Bíbélì: Iṣi 14:6
JÍ!
Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ ẹ rò pé ìlànà yìí lè ran àwọn tọkọtaya lọ́wọ́ láti yanjú àìgbọ́ra-ẹni-yé tó bá wáyé láàárín wọn?
Ka Bíbélì: Jak 1:19
Fi ìwé lọni: [Fi àpilẹ̀kọ tó bẹ̀rẹ̀ lójú ìwé 10 han onílé.] Àpilẹ̀kọ yìí sọ àwọn ìlànà Bíbélì míì lórí kókó yìí.
ÀWỌN ÌWÉ ÀṢÀRÒ KÚKÚRÚ
Béèrè ìbéèrè: Ẹ jọ̀wọ́, ẹ wo ìbéèrè yìí. [Ka ìbéèrè tó wà níwájú ìwé àṣàrò kúkúrú náà àti onírúurú ìdáhùn tó wà níbẹ̀.] Kí lèrò yín nípa rẹ̀?
Ka Bíbélì: [Èyí tó wà lójú ìwé 2 nínú ìwé àṣàrò kúkúrú náà]
Fi ìwé lọni: Ìwé yìí sọ àǹfààní tí ọ̀rọ̀ Bíbélì yìí lè ṣe fún yín.
KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ