June 20 sí 26
SÁÀMÙ 45-51
Orin 67 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jèhófà Kò Ní Fi Ẹni Tó Ní Ìròbìnújẹ́ Ọkàn Sílẹ̀”: (10 min.)
Sm 51:1-4
—Dáfídì kábàámọ̀ gan-an pé òun dẹ́ṣẹ̀ sí Jèhófà (w93 3/15 ojú ìwé 10 àti 11 ìpínrọ̀ 9 sí 13) Sm 51:7-9
—Dáfídì fẹ́ kí Jèhófà dárí ji òun kó bàa lè máa láyọ̀ bíi ti tẹ́lẹ̀ (w93 3/15 ojú ìwé 12 àti 13 ìpínrọ̀ 18 sí 20) Sm 51:10-17
—Dáfídì mọ̀ pé Jèhófà máa dárí ji ẹni tó bá ronú pìwà dà tọkàntọkàn (w15 6/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 6; w93 3/15 ojú ìwé 14 sí 17 ìpínrọ̀ 4 sí 16)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sm 45:4
—Òtítọ́ tó ga jù lọ wo la gbọ́dọ̀ gbèjà? (w14 2/15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 11) Sm 48:
12, 13—Iṣẹ́ wo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí sọ pé a gbọ́dọ̀ ṣe? (w15 7/15 ojú ìwé 9 ìpínrọ̀ 13) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 49:10–50:6
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.3 ojú ìwé 10 àti 11
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) g16.3 ojú ìwé 10 àti 11
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 3 ìpínrọ̀ 1
—Ní ìparí ìkẹ́kọ̀ọ́, jẹ́ kí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo tá a pè ní Ta ni Òǹṣèwé Bíbélì?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 98
“Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso”: (15 min.) Ìbéèrè àti ìdáhùn. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo tá a pè ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ti Kọjá, Ìjọba Ọlọ́run Ṣì Ń Ṣàkóso láti ìbẹ̀rẹ̀ dé apá tá a pè ní “Ìdálẹ́kọ̀ọ́ Ọlọ́jọ́ Kan.” (Wo abẹ́ ÀWỌN ÌTẸ̀JÁDE > ÀWỌN FÍDÍÒ.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 18 ìpínrọ̀ 1 sí 13
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 109 àti Àdúrà