June 27 sí July 3
SÁÀMÙ 52-59
Orin 38 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ju Ẹrù Ìnira Rẹ Sọ́dọ̀ Jèhófà”: (10 min.)
Sm 55:2, 4, 5, 16-18
—Àwọn ìgbà kan wà tí ìdààmú ọkàn bá Dáfídì gan-an (w06 6/1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 3; w96 4/1 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 2) Sm 55:
12-14 —Ọmọ Dáfídì àti ọ̀rẹ́ Dáfídì kan tó fọkàn tán dìtẹ̀ mọ́ ọn (w96 4/1 ojú ìwé 30 ìpínrọ̀ 1) Sm 55:22
—Ó dá Dáfídì lójú pé Jèhófà máa ràn òun lọ́wọ́ (w06 6/1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 4; w99 3/15 ojú ìwé 22 sí 23)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Sm 56:8
—Kí ni ọ̀rọ̀ náà “fi omijé mi sínú ìgò awọ rẹ” túmọ̀ sí? (w09 6/1 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 1; w08 10/1 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 3) Sm 59:
1, 2 —Kí ni ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Dáfídì kọ́ wa nípa àdúrà? (w08 3/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 13) Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?
Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 52:1–53:6
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi ọ̀kan lára àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú lọni. Fi àmì ìlujá tó wà lẹ́yìn rẹ̀ han onílé.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ṣe àṣefihàn bí a ṣe lè ṣe ìpadàbẹ̀wò ẹni tó gba ìwé àṣàrò kúkúrú.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 3 ìpínrọ̀ 2 àti 3
—Ní ìparí ìkẹ́kọ̀ọ́, jẹ́ kí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/yo tá a pè ní Báwo La Ṣe Mọ̀ Pé Òótọ́ ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì?
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Orin 56
Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (7 min.)
“Ọlọ́run Ni Olùrànlọ́wọ́ Mi”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí bó bá ti lè ṣeé ṣe tó, èyí á mú kí gbogbo wa lè jàǹfààní látinú ìrírí àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa. (Ro 1:12) Gba àwọn ará níyànjú láti máa lo Ìwé Ìwádìí láti fi wá ohun tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ nígbà tí wọ́n bá níṣòro.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 18 ìpínrọ̀ 14 sí 21 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 161
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 121 àti Àdúrà