Àwọn ará ń gbádùn ìfararora lórílẹ̀-èdè Myanmar

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI June 2019

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí ohun tá a lè ṣe láti la òpin ayé yìí já.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Àkàwé” Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀

Kí ni àwọn ìyàwó Ábúráhámù méjèèjì dúró fún, ìyẹn Sárà àti Hágárì? Báwo lo ṣe lè jàǹfààní látinú májẹ̀mú tuntun yìí?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Iṣẹ́ Àbójútó Jèhófà àti Ohun Tó Wà Fún

Kí ni iṣẹ́ àbójútó Jèhófà, báwo lo sì ṣe lè kọ́wọ́ tì í?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jẹ́ Kí Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Túbọ̀ Máa Mérè Wá

Kí làwọn nǹkan tó o lè ṣe kí ìdákẹ́kọ̀ọ́ rẹ bàa lè túbọ̀ nítumọ̀?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”

Ọmọ ogun ni àwa Kristẹni. Mọ ọ̀kọ̀ọ̀kan ìhámọ́ra ogun tẹ̀mí tó o ní, àti ohun tí wọ́n túmọ̀ sí.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Kí Ni Jèhófà Máa Fẹ́ Kí N Ṣe?

Báwo lo ṣe lè máa fòye mọ ohun tí ìfẹ́ Jèhófà jẹ́, kó o sì máa gbé níbàámu pẹ̀lú ìfẹ́ rẹ̀?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ẹ Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Nípa Ohunkóhun”

Oríṣiríṣi nǹkan ló lè fa àníyàn fún wa láwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí. Kí ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti má máa ṣàníyàn?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Fọgbọ́n Yan Eré Ìnàjú Tí Wàá Máa Ṣe

Báwo lo ṣe lè ṣe ohun tó máa múnú Ọlọ́run dùn nígbà tó o bá fẹ́ ṣeré ìnàjú?