June 17-23
ÉFÉSÙ 4-6
Orin 71 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”: (10 min.)
Ef 6:11-13—A nílò ààbò kúrò lọ́wọ́ Sátánì àtàwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀ (w18.05 27 ¶1)
Ef 6:14, 15—Fi òtítọ́, òdodo àti ìhìn rere àlàáfíà dáàbò bo ara rẹ (w18.05 28-29 ¶4, 7, 10)
Ef 6:16, 17—Fi ìgbàgbọ́, ìrètí ìgbàlà àti Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run dáàbò bo ara rẹ (w18.05 29-31 ¶13, 16, 20)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ef 4:17-32 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? lẹ́yìn náà, kẹ́ ẹ jíròrò rẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Kí Ni Jèhófà Máa Fẹ́ Kí N Ṣe?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ẹ Máa Fi Òye Mọ Ohun Tí Ìfẹ́ Jèhófà Jẹ́ (Le 19:18).
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶9-15
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 34 àti Àdúrà