Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÉFÉSÙ 4-6

“Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”

“Ẹ Gbé Gbogbo Ìhámọ́ra Ogun Láti Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Wọ̀”

6:​11-17

Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù fi àwa Kristẹni wé ọmọ ogun kan tó wà lójú ogun. Àwọn “ọmọ ogun ẹ̀mí burúkú” ni ọ̀tá àwa Kristẹni. Lóòótọ́, ó lè jọ bíi pé a ò lágbára tàbí pé a ò lẹ́ni lẹ́yìn, àmọ́ tá a bá “gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀,” Jèhófà máa ràn wá lọ́wọ́ láti jagun náà ní àjà ṣẹ́gun.

Kọ ohun tí ìhámọ́ra kọ̀ọ̀kan jẹ́ àtohun tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dúró fún

FI ṢÀṢÀRÒ: Ṣé gbogbo ìhámọ́ra ogun ni mo ní?