June 24-30
FÍLÍPÌ 1-4
Orin 33 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Nípa Ohunkóhun”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Fílípì.]
Flp 4:6—Àdúrà lòògùn àníyàn (w17.08 10 ¶10)
Flp 4:7—Jẹ́ kí “àlàáfíà Ọlọ́run” máa ṣọ́ ẹ (w17.08 10 ¶7; 12 ¶16)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Flp 4:10-23 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 6 ¶3-4 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ṣé Fóònù tàbí Tablet Ò Tíì Di Bárakú fún Ẹ?: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni àwọn ẹ̀rọ ìgbàlódé wúlò fún? Jàǹbá wo ló lè ṣe fún wa tá a bá jẹ́ kó di bárakú fún wa? Báwo lo ṣe lè mọ̀ tí wọ́n bá ti ń di bárakú fún ẹ? Àwọn nǹkan wo lo lè ṣe láti lè rí i dájú pé o “wádìí dájú àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù”? (Flp 1:10)
“Fọgbọ́n Yan Eré Ìnàjú Tí Wàá Máa Ṣe”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Eré Ìnàjú Wo Ló Yẹ Kí N Yàn Láàyò?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 7 ¶16-20 àti àfikún Kí Ni Ṣìọ́ọ̀lù àti Hédíìsì?
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 76 àti Àdúrà