Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | FÍLÍPÌ 1-4

“Ẹ Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Nípa Ohunkóhun”

“Ẹ Má Ṣe Máa Ṣàníyàn Nípa Ohunkóhun”

4:​6, 7

  • Àdúrà ni oògùn àníyàn

  • Tá a bá gbàdúrà, tá a sì ní ìgbàgbọ́, Jèhófà máa fún wa ní àlàáfíà “tó kọjá gbogbo òye”

  • Lóòótọ́ ó lè jọ pé kò sí ọ̀nà àbáyọ sí àwọn ìṣòro wa, àmọ́ Jèhófà lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara dà á. Ó tiẹ̀ lè ṣe kọjá ohun tá a rò pàápàá.​—1Kọ 10:13