Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÉFÉSÙ 1-3

Iṣẹ́ Àbójútó Jèhófà àti Ohun Tó Wà Fún

Iṣẹ́ Àbójútó Jèhófà àti Ohun Tó Wà Fún

1:​8-10

Jèhófà ṣètò iṣẹ́ yìí láti mú kí gbogbo ẹ̀dá rẹ̀ olóye wà ní ìṣọ̀kan.

  • Ọlọ́run múra ìjọ àwọn ẹni àmì òróró sílẹ̀ láti lọ gbé lọ́run, wọ́n sì máa wà lábẹ́ ìdarí Jésù Kristi tí Ọlọ́run yàn ṣe Orí wọn

  • Ọlọ́run ń múra àwọn tó máa gbé lórí ilẹ̀ ayé sílẹ̀, lábẹ́ Ìjọba Mèsáyà

Àwọn ọ̀nà wo ni mo lè gbà pa kún ìṣọ̀kan tó wà nínú ètò Jèhófà?