Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

June 3-​9

GÁLÁTÍÀ 4-6

June 3-​9
  • Orin 16 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  •  ‘Àkàwé’ Kan àti Ìtumọ̀ Rẹ̀”: (10 min.)

    • Ga 4:​24, 25​—Hágárì dúró fún orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì tó wà lábẹ́ Májẹ̀mú Òfin (it-1 1018 ¶2)

    • Ga 4:​26, 27​—Sárà dúró fún “Jerúsálẹ́mù ti òkè,” ìyẹn apá ti òkè ọ̀run lára ètò Jèhófà (w14 10/15 10 ¶11)

    • Ga 4:​28-31​—“Ọmọ” Jerúsálẹ́mù ti òkè máa bù kún àwọn tó bá jẹ́ onígbọràn

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ga 4:6​—Kí ni ọ̀rọ̀ Hébérù tàbí Árámáíkì náà ábà túmọ̀ sí? (w09 4/1 13)

    • Ga 6:17​—Kí ló ṣeé ṣe kí “àpá ẹrú Jésù” tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù sọ pé ó wà lára òun túmọ̀ sí? (w10 11/1 15)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ga 4:​1-20 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 110

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (8 min.)

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (7 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 6 ¶14-20

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 40 àti Àdúrà