Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

March 28 sí April 3

JÓÒBÙ 11-15

March 28 sí April 3
  • Orin 111 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 134

  • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (5 min.)

  • Ìràpadà Mú Kí Àjíǹde Ṣeé Ṣe”: (10 min.) Ìjíròrò. Ní ìparí ìjíròrò yìí, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a wò ní Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Kọ́kọ́ Máa Wá Ìjọba Ọlọ́run!” ti ọdún 2014.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 12 ìpínrọ̀ 1 sí 12 (30 min.)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 33 àti Àdúrà