Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an

Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an

Wo fídíò náà Òpin Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ti Sún Mọ́ Gan-an, kó o sì dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí tó dá lórí Mátíù 24:34.

  • Kí ni “gbogbo nǹkan wọ̀nyí”?

  • Báwo ni Ẹ́kísódù 1:6 ṣe ràn wá lọ́wọ́ láti mọ ìtumọ́ ọ̀rọ̀ náà “ìran”?

  • Ìran wo ní pàtàkì ni Jésù ń tọ́ka sí?

  • Àwùjọ méjì wo ló para pọ̀ di “ìran yìí”?

  • Báwo ni ọ̀rọ̀ Jésù ṣe fi hàn pé òpin ètò àwọn nǹkan yìí ti sún mọ́ gan-an?