Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 24

Máa Wà Lójúfò Nípa Tẹ̀mí ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí

Máa Wà Lójúfò Nípa Tẹ̀mí ní Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn Yìí

24:39

Ọ̀pọ̀ èèyàn lóde òní ti jẹ́ kí ìgbé ayé ìdẹ̀rùn tí wọ́n ń lépa dí wọn lọ́wọ́ láti ṣe àwọn nǹkan tẹ̀mí. Báwo làwọn Kristẹni tó wà lójúfò nípa tẹ̀mí ṣe yàtọ̀ sí àwọn èèyàn ayé tó bá dọ̀rọ̀ ojú tí wọ́n fi ń wo . . .

  • ilé ẹ̀kọ́ gíga?

  • eré ìtura?

  • iṣẹ́?

  • àwọn nǹkan tara?