Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Ọlọ́run fẹ́ fún àwa èèyàn?

Bíbélì: Jẹ 1:28

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa?

Bíbélì: Ais 55:11

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ayé ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe àwọn nǹkan tó fẹ́ ṣe?

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo ni ayé ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe àwọn nǹkan tó fẹ́ ṣe?

Bíbélì: Sm 37:10, 11

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí la gbọ́dọ̀ ṣe ká tó lè gbádùn àwọn ìlérí Ọlọ́run yẹn?

ÌKÉSÍNI SÍ ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (March 23–April 19):

A fẹ́ pè yín sí ìpàdé pàtàkì kan. Ìwé ìkésíni tiyín rèé. Ní Friday, April 19, ọ̀pọ̀ èèyàn kárí ayé máa pé jọ láti ṣe ìrántí ikú Jésù Kristi. Ẹ máa rí àkókò àti ibi tá a ti máa ṣe ìpàdé náà nínú ìwé yìí. A tún fẹ́ kẹ́ ẹ wá gbọ́ àsọyé kan ní ọ̀sẹ̀ tó ṣáájú ìgbà yẹn, àkòrí rẹ̀ ni “Sapá Kó O Lè Ní Ìyè Tòótọ́!”

Tí Ẹni Náà Bá Nífẹ̀ẹ́ Sí Ọ̀rọ̀ Rẹ, Fi Ìbéèrè Yìí Sílẹ̀: Kí nìdí tí Jésù fi kú?