Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

March 11-17

RÓÒMÙ 15-16

March 11-17
  • Orin 33 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Bẹ Jèhófà Pé Kó Fún Ẹ Ní Ìfaradà Kó sì Tù Ẹ́ Nínú”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Ro 15:27​—Báwo ni àwọn Kèfèrí tó di Kristẹni ṣe jẹ́ “ajigbèsè” sí àwọn Kristẹni tó wà ní Jerúsálẹ́mù? (w89 12/1 24 ¶3)

    • Ro 16:25​—Kí ni “àṣírí ọlọ́wọ̀ tí a ti pa mọ́ ní ìdákẹ́jẹ́ẹ́ tipẹ́tipẹ́”? (it-1 858 ¶5)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 15:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 10)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 129

  • Bí Jèhófà Ṣe Ń “Pèsè Ìfaradà àti Ìtùnú”: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà (lára àwọn fídíò tó wà ní abala BÍBÉLÌ). Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí:

    • Ẹ̀kọ́ wo lo rí kọ́ nípa bá a ṣe ń rí ìtùnú gbà?

    • Ẹ̀kọ́ wo lo rí kọ́ nípa bá a ṣe lè fún àwọn míì ní ìṣírí?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 3 ¶21-24

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 34 àti Àdúrà