Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | RÓÒMÙ 15-16

Bẹ Jèhófà Pé Kó Fún Ẹ Ní Ìfaradà Kó sì Tù Ẹ́ Nínú

Bẹ Jèhófà Pé Kó Fún Ẹ Ní Ìfaradà Kó sì Tù Ẹ́ Nínú

15:4-7

Ọ̀kan lára àwọn nǹkan tí Jèhófà máa ń lò láti pèsè ìtùnú àti ìfaradà fún wa ni Bíbélì Ọ̀rọ̀ rẹ̀. Báwo ni àpẹẹrẹ àwọn tó wà nínú Bíbélì yìí ṣe fún ẹ ní ìṣírí àti ìtùnú?

  • Nóà

  • Jósẹ́fù

  • Dáfídì