March 18-24
1 KỌ́RÍŃTÌ 1-3
Orin 127 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ṣé Ẹni Tara Ni Ẹ́ Tàbí Ẹni Tẹ̀mí?”: (10 min.)
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Kọ́ríńtì Kìíní.]
1Kọ 2:14—Kí ló túmọ̀ sí pé kéèyàn jẹ́ “ènìyàn ti ara”? (w18.02 19 ¶4-5)
1Kọ 2:15, 16—Kí ló túmọ̀ sí pé kéèyàn jẹ́ “ènìyàn ti ẹ̀mí”? (w18.02 19 ¶6; 22 ¶15)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
1Kọ 1:20—Báwo ni Ọlọ́run ṣe “sọ ọgbọ́n ayé di òmùgọ̀”? (it-2 1193 ¶1)
1Kọ 2:3-5—Báwo ni àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù ṣe lè ràn wá lọ́wọ́? (w08 7/15 27 ¶6)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 1:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́—Fídíò: (5 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni han onílé. (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bó O Ṣe Lè Kọ Lẹ́tà”: (8 min.) Ìjíròrò.
A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pe Àwọn Èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi ní Saturday, March 23: (7 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní ìwé ìkésíni náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a máa lò. Sọ ètò tí ìjọ ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 4 ¶1-9
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 51 àti Àdúrà