Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

March 25-​31

1 KỌ́RÍŃTÌ 4-6

March 25-​31
  • Orin 123 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”: (10 min.)

    • 1Kọ 5:1, 2​—Àwọn tó wà ní ìjọ Kọ́ríńtì ń fàyè gba oníwà àìtọ́ kan tí kò ronú pìwà dà

    • 1Kọ 5:5-8, 13​—Pọ́ọ̀lù sọ pé kí ìjọ yọ “ìwúkàrà” náà kúrò láàárín wọn, kí wọ́n sì fi ẹni tó hùwà àìtọ́ náà lé Sátánì lọ́wọ́ (it-2 230, 869-870)

    • 1Kọ 5:9-11​—Ẹnì kankan nínu ìjọ ò gbọdọ̀ bá oníwà àìtọ́ tí kò ronú pìwà dà náà kẹ́gbẹ́ (lv 207 ¶1-3, àfikún “Ọwọ́ Tó Yẹ Ká Fi Mú Ẹni Tí Wọ́n Bá Yọ Lẹ́gbẹ́.”)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Kọ 4:9​—Báwo ni àwọn èèyàn tó jẹ́ ìránṣẹ́ Ọlọ́run ṣe di “ìran àpéwò ní gbọ̀ngàn ìwòran” fún àwọn áńgẹ́lì? (w09 5/15 24 ¶16)

    • 1Kọ 6:3​—Kí ni Pọ́ọ̀lù ń tọ́ka sí nígbà tó kọ̀wé pé: “Àwa ni yóò ṣèdájọ́ àwọn áńgẹ́lì”? (it-2 211)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 6:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI