Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 KỌ́RÍŃTÌ 4-6

“Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”

“Ìwúkàrà Díẹ̀ Ní Í Mú Gbogbo Ìṣùpọ̀ Di Wíwú”

5:1, 2, 5-11, 13

Kí nìdí tá a fi máa ń sọ pé ìfẹ́ ló mú kí Jèhófà ṣètò ìyọlẹ́gbẹ́ nígbà tó jẹ́ pé ó máa ń dunni gan-an tó bá ṣẹlẹ̀?

Ìyọlẹ́gbẹ́ fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ . . .

  • Jèhófà, a sì ń bọlá fún orúkọ mímọ́ rẹ̀.​—1Pe 1:15, 16

  • àwọn ará ìjọ, a sì fẹ́ dáàbò bò wọ́n kí ìwà burúkú máa bàa gbilẹ̀.​—1Kọ 5:6

  • ẹni tó dẹ́ṣẹ̀ náà, a sì fẹ́ ràn án lọ́wọ́, ká sì pe orí rẹ̀ wálé.​—Heb 12:11

Tí wọ́n bá yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́ nínú ìdílé Kristẹni kan, báwo lo ṣe lè ràn wọ́n lọ́wọ́?