March 4-10
RÓÒMÙ 12-14
Orin 106 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tó Túmọ̀ Sí Láti Fi Ìfẹ́ Hàn Síra Wa”: (10 min.)
Ro 12:10—Ká ní ìfẹ́ni fáwọn ará wa (it-1 55)
Ro 12:17-19—Tẹ́nì kan bá ṣẹ̀ wá, ká má gbẹ̀san (w09 10/15 8 ¶3; w07 7/1 24-25 ¶12-13)
Ro 12:20, 21—Fi ire ṣẹ́gun ibi (w12 11/15 29 ¶13)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Ro 12:1—Kí ni ẹsẹ yìí túmọ̀ sí? (lv 64 ¶5-6)
Ro 13:1—Ọ̀nà wo ni a gbà gbé àwọn aláṣẹ onípò gíga “dúró sí àwọn ipò wọn aláàlà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run”? (w08 6/15 31 ¶4)
Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ro 13:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Lo Ìbéèrè Bó Ṣe Yẹ, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 3 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w11 9/1 21-22—Àkòrí: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Káwa Kristẹni Máa San Owó Orí Tí Wọn Bá Tiẹ̀ Ń Fi Owó Yẹn Ṣe Àwọn Nǹkan Tí Kò Tọ́? (th ẹ̀kọ́ 3)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 3 ¶13-20
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 57 àti Àdúrà