Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 25-26

Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀

Ísọ̀ Ta Ogún Ìbí Rẹ̀

25:27-34

Ísọ̀ “kò mọyì àwọn ohun mímọ́.” (Heb 12:16) Ìdí nìyẹn tó fi ta ogún ìbí rẹ̀, tó sì tún fẹ́ àwọn obìnrin tí kò sin Jèhófà.​—Jẹ 26:34, 35.

BI ARA RẸ PÉ: ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé mo mọyì àwọn ohun mímọ́ yìí?’

  • Àjọṣe mi pẹ̀lú Jèhófà

  • Ẹ̀mí mímọ́

  • Bá a ṣe ń jẹ́ orúkọ mọ́ Jèhófà

  • Iṣẹ́ ìwàásù

  • Àwọn ìpàdé wa

  • Ìgbéyàwó