Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

March 2-8
  • Orin 89 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò”: (10 min.)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 22:5—Kí ló mú kí Ábúráhámù sọ fáwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé òun àti Ísákì máa pa dà wá bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó mọ̀ pé òun máa tó fi Ísákì rúbọ? (w16.02 7 ¶13)

    • Jẹ 22:12—Báwo ni ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé kì í ṣe gbogbo ìgbà ni Jèhófà máa ń lo agbára tó ní láti mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú? (it-1 853 ¶5-6)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 22:1-18 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI