Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

March 23-29
  •  Orin 10 àti Àdúrà

  •  Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I”: (10 min.)

    • Jẹ 27:6-10​—Rèbékà ran Jékọ́bù lọ́wọ́ láti gba ìbùkún tó tọ́ sí i (w04 4/15 11 ¶4-5)

    • Jẹ 27:18, 19​—Jékọ́bù mú kí bàbá rẹ̀ ronú pé òun ni Ísọ̀ (w07 10/1 31 ¶2-3)

    • Jẹ 27:27-29​—Ísákì ronú pé Jékọ́bù ni àkọ́bí, ó sì súre fún un (it-1 341 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 27:46–28:2​—Ẹ̀kọ́ wo làwọn tọkọtaya lè rí kọ́ látinú ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí? (w06 4/15 6 ¶2-3)

    • Jẹ 28:12, 13​—Kí ni “àtẹ̀gùn” tàbí àkàsọ̀ tí Jékọ́bù rí nínú àlá rẹ̀ fi hàn? (w04 1/15 28 ¶6)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 27:1-23 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ni akéde náà ṣe tó fi hàn pé ó tẹ́tí sí onílé náà nígbà tó ń sọ̀rọ̀? Kí ló fi hàn pé akéde náà lo Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà tó dáa?

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 17 (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 34

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 17 ¶9-12

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 28 àti Àdúrà