Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 27-28

Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I

Jékọ́bù Gba Ìbùkún Tó Tọ́ Sí I

27:6-10, 18, 19, 27-29

Àsọtẹ́lẹ̀ kan ti wà pé Jékọ́bù máa gba ìbùkún tó jẹ́ ti àkọ́bí.

  • 27:28​—Jèhófà fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jékọ́bù ní ilẹ̀ ọlọ́ràá “tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn.”​—Di 26:15

  • 27:29​—Nígbà tó yá, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Jékọ́bù lágbára ju àwọn ọmọ Édómù tó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Ísọ̀ lọ.​—Jẹ 25:23; 2Sa 8:14

  • 27:29​—Jèhófà gégùn-ún fún àwọn ọmọ Édómù torí pé wọ́n kórìíra àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, orílẹ̀-èdè wọn sì pa run pátápátá.​—Isk 25:12-14