Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Jèhófà Máa Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Wàásù Lójú Àtakò

Jèhófà Máa Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Wàásù Lójú Àtakò

Lọ́pọ̀ ìgbà, ohun táwọn alátakò ń fẹ́ ni pé kí wọ́n dá iṣẹ́ ìwàásù wa dúró. Àmọ́, tá a bá jẹ́ adúróṣinṣin lójú àtakò tó le koko, ìyẹn máa fògo fún Jèhófà.

Ẹ WO FÍDÍÒ A GBỌ́RỌ̀ LÁTẸNU ARÁKÙNRIN DMITRIY MIKHAYLOV, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Báwo ni wọ́n ṣe ṣenúnibíni sí Arákùnrin Mikhaylov?

  • Báwo ni Jèhófà ṣe ran Arákùnrin Mikhaylov lọ́wọ́ láti fara dà á?

  • Báwo ni Jèhófà ṣe lo inúnibíni tí wọ́n ṣe sí Arákùnrin Mikhaylov láti jẹ́ káwọn ẹlẹ́wọ̀n tó kù gbọ́ ìwàásù?