Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní

Ẹnì Kan Lè Ṣe Ọ̀pọ̀ Èèyàn Láǹfààní

Àwọn ọmọ Móábù mú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì dẹ́ṣẹ̀ (Nọ 25:​1, 2; lv 97 ¶1-2)

Inú Jèhófà ò dùn sáwọn ọmọ Ísírẹ́lì torí pé wọ́n di aláìṣòótọ́, wọ́n sì mọ tara wọn nìkan (Nọ 25:​3-5; lv 98 ¶4)

Ìbínú Jèhófà rọlẹ̀ torí pé ẹnì kan fi ìgboyà gbé ìgbésẹ̀ (Nọ 25:​6-11)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn nǹkan wo ló ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀ tá gba pé kí n jẹ́ onígboyà kí n sì yàtọ̀ sáwọn tó kù?’