April 5-11
NỌ́ŃBÀ 17-19
Orin 80 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Nọ 18:19—Kí ni ìtumọ̀ “májẹ̀mú iyọ̀ tó máa wà títí lọ”? (g02 6/8 26 ¶2)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 18:1-13 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Jésù—Mt 20:28. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 6)
Àsọyé: (5 min.) w18.01 18 ¶4-6—Àkòrí: Kí Nìdí Tá A Fi Ń Fún Jèhófà Ní Nǹkan? (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 7 ¶8-15 àti àpótí 7A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 7 àti Àdúrà