ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
Àwọn tí Jèhófà yàn láti jẹ́ olórí ló máa ń múpò iwájú nínú ìjọsìn (Nọ 7:10; it-1 497 ¶3)
Àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà gbọ́dọ̀ wà létòlétò (Nọ 7:11; it-2 796 ¶1)
Jèhófà kì í béèrè ohun tó ju agbára ẹnì kọ̀ọ̀kan lọ (Nọ 8:25, 26; w04 8/1 25 ¶1)
Bí Jèhófà ṣe ṣètò àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nígbà àtijọ́, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe ṣètò àwa èèyàn rẹ̀ lónìí. Àmọ́, ó ń kíyè sí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa, ó ń rí gbogbo bá a ṣe ń sapá ká lè máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀.