March 15-21
NỌ́ŃBÀ 11-12
Orin 46 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Ráhùn?”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Nọ 11:7, 8—Àwọn nǹkan wo la lè sọ nípa Jèhófà tá a bá ronú nípa bí mánà ṣe rí? (it-2 309)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 11:1-15 (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Tẹ́ni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ìrántí Ikú Jésù, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí, fọgbọ́n bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹnì kan tó wá síbẹ̀, kó o sì dáhùn ìbéèrè tó béèrè nípa bá a ṣe ṣèpàdé náà. (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ fún Ìrántí Ikú Kristi?”: (15 min.) Ìjíròrò. Sọ àwọn ìfilọ̀ tẹ́ ẹ bá ní nípa bẹ́ ẹ ṣe máa ṣe Ìrántí Ikú Kristi. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Bó O Ṣe Lè Ṣe Búrẹ́dì Ìrántí Ikú Kristi.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 6 ¶7-13 àti àpótí 6A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 70 àti Àdúrà