Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Ráhùn?

Kí Nìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Ráhùn?

Inú Jèhófà kì í dùn sáwọn tó bá ń ráhùn (Nọ 11:1; w01 6/15 17 ¶20)

Aláìmoore àti onímọ̀-tara-ẹni-nìkan lẹni tó bá ń ráhùn (Nọ 11:​4-6; w06 7/15 15 ¶7)

Tá a bá ń ráhùn, ó lè jẹ́ kí nǹkan sú àwọn míì (Nọ 11:​10-15; it-2 719 ¶4)

Nǹkan ò rọrùn fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì nínú aginjù lóòótọ́, síbẹ̀ ó yẹ kí wọ́n máa dúpẹ́ torí ọ̀pọ̀ nǹkan ni Jèhófà ti ṣe fún wọn. Táwa náà bá ń fara balẹ̀ ronú lórí ọ̀pọ̀ nǹkan tí Jèhófà ti ṣe fún wa, a ò ní máa ráhùn.