March 29–April 4
NỌ́ŃBÀ 15-16
Orin 101 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Nọ 15:32-35—Kí la rí kọ́ látinú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w98 9/1 20 ¶1-2)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 15:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Jésù—Mt 16:16. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 1)
Àsọyé: (5 min.) w15 5/15 14 ¶5-6—Àkòrí: Ìyàtọ̀ Wo Ló Wà Nínú Kéèyàn Máa Yangàn àti Kéèyàn Máa Gbéra Ga? (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Má Ṣe Fara Wé Àwọn Aláìdúróṣinṣin”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Má Ṣe Fara Wé Àwọn Aláìdúróṣinṣin.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 7 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 7
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 126 àti Àdúrà