Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

March 8-14

NỌ́ŃBÀ 9-10

March 8-14
  • Orin 31 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Tẹ́ni náà bá nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ìrántí Ikú Jésù, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó). (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Pe ẹni tẹ́ ẹ jọ ń ṣiṣẹ́ tàbí ọmọléèwé rẹ tó o ti bá sọ̀rọ̀ nígbà kan rí wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) bhs 214, àlàyé ìparí ìwé 16​—Pe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ wá sí Ìrántí Ikú Kristi, kó o sì fi Bíbélì ṣàlàyé ìdí tí kò fi yẹ kó jẹ búrẹ́dì tàbí mu wáìnì. (th ẹ̀kọ́ 17)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 84

  • Àyípadà Tó Wáyé ní Bẹ́tẹ́lì Ń Mú Kí Iṣẹ́ Ìwàásù Tẹ̀ Síwájú: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé: Ìfilọ̀ wo ni ètò Ọlọ́run ṣe níbi ìpàdé ọdọọdún 2015, àwọn nǹkan méjì wo ló sì mú kí wọ́n ṣe àyípadà yìí? Àwọn àyípadà wo ni ètò Ọlọ́run ṣe ní Bẹ́tẹ́lì, àǹfààní wo la sì rí níbẹ̀? Báwo ni ìfilọ̀ yẹn ṣe kan Bẹ́tẹ́lì tuntun tí wọ́n ń kọ́ nílẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì? Báwo làwọn àyípadà yẹn ṣe jẹ́ kó túbọ̀ dá wa lójú pé Jèhófà ló ń darí wa?

  • Ìdí Tá A Fi Wá sí Bẹ́tẹ́lì: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 6 ¶1-6 àti fídíò ohun tó wà ní orí 6

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 12 àti Àdúrà