Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀

Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀

Jèhófà ló máa ń pinnu ibi tó yẹ káwọn èèyàn rẹ̀ lọ àti ìgbà tó yẹ kí wọ́n gbéra (Nọ 9:​17, 18; it-1 398 ¶3)

Ẹsẹ̀kẹsẹ̀ làwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ìtọ́ni Jèhófà (Nọ 9:​21, 22; w11 4/15 4-5)

Àwọn èèyàn aláìpé ni Jèhófà máa ń lò láti fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní ìtọ́ni (Nọ 10:​5-8)

Tá a bá ń ṣègbọràn sáwọn tí Jèhófà ń lò láti darí wa, Jèhófà là ń ṣègbọràn sí.