April 18-24
1 SÁMÚẸ́LÌ 23-24
Orin 114 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Sa 23:16, 17—Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jónátánì? (w17.11 27 ¶11)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 23:24–24:7 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 13)
Àsọyé: (5 min.) w19.03 23-24 ¶12-15—Àkòrí: Máa Ní Sùúrù Fáwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Bópẹ́bóyá, Kò Sí Ìṣòro Tí Ò Ní Dópin”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Èèyàn Tó Wà Níṣọ̀kan Nínú Ayé Tó Pín Yẹ́lẹyẹ̀lẹ.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr Àkópọ̀ Àwọn Àtúnṣe Tó Bá Òye Wa, ìbéèrè 5-8
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 96 àti Àdúrà