Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

April 4-10
  • Orin 90 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò: (2 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Lẹ́yìn tí Ìrántí Ikú Kristi parí, fọgbọ́n bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ẹnì kan tó o pè. Kó o wá dáhùn ìbéèrè tó béèrè nípa bẹ́ ẹ ṣe ṣèpàdé náà. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 04 kókó 3 (th ẹ̀kọ́ 20)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI