March 21-27
1 SÁMÚẸ́LÌ 16-17
Orin 7 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Sa 16:14—Kí ló túmọ̀ sí nígbà tí Bíbélì sọ pé ‘Jèhófà jẹ́ kí ẹ̀mí búburú’ máa da Sọ́ọ̀lù láàmú? (it-2 871-872)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 16:1-13 (th ẹ̀kọ́ 5)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (2 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi: (3 min.) Pe ẹni tẹ́ ẹ jọ ń ṣiṣẹ́, ọmọ iléèwé rẹ tàbí mọ̀lẹ́bí rẹ tó o ti wàásù fún nígbà kan rí wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ rẹ, tó sì gba ìwé ìkésíni. Sọ fún ẹni náà pé kó lọ sórí ìkànnì wa. (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ọ̀nà Mẹ́ta Tá A Lè Gbà Fi Hàn Pé A Gbára Lé Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Kò Yẹ Ká Bẹ̀rù Inúnibíni.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 22 ¶10-22
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 13 àti Àdúrà