March 28–April 3
1 SÁMÚẸ́LÌ 18-19
Orin 36 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Sa 19:23, 24—Ọ̀nà wo ló ṣeé ṣe kí Ọba Sọ́ọ̀lù gbà ṣe “bíi wòlíì”? (it-2 695-696)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 18:25–19:7 (th ẹ̀kọ́ 11)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́.
Àsọyé: (5 min.) km 1/03 1—Àkòrí: Iṣẹ́ Kan Tó Ń Béèrè Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀. (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 22 ¶23-31 àti àpótí 22A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 2 àti Àdúrà