ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yin Dáfídì (1Sa 18:5-7; w04 4/1 15 ¶4)
Jèhófà jẹ́ kí Dáfídì ṣàṣeyọrí nínú gbogbo ohun tó ṣe (1Sa 18:14)
Dáfídì lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ láìka àṣeyọrí tó ṣe sí (1Sa 18:22, 23; w18.01 28 ¶6-7)
Kí nìdí tó fi yẹ ká lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀ tí Jèhófà bá mú ká ṣàṣeyọrí? Kí lá jẹ́ ká lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀?