April 17-23
2 KÍRÓNÍKÀ 10-12
Orin 103 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Tá A Bá Tẹ̀ Lé Ìmọ̀ràn Tó Dáa Ó Máa Ṣe Wá Láǹfààní”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Kr 11:15—Kí ló ṣeé ṣe kí ọ̀rọ̀ náà “àwọn ẹ̀mí èṣù tó rí bí ewúrẹ́” túmọ̀ sí? (it-1 966-967)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 10:1-15 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 6)
Àsọyé: (5 min.) be 69 ¶4-5—Àkòrí: Kí Ló Yẹ Kó O Ṣe Tí Akẹ́kọ̀ọ́ Rẹ Bá Ní Kó O Gba Òun Nímọ̀ràn? (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Bá A Ṣe Lè Lo Àwọn Fídíò Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì”: (5 min.) Àsọyé àti fídíò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ohun Tó O Máa Gbádùn Nínú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Rẹ.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 43
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 121 àti Àdúrà