Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Tá A Bá Tẹ̀ Lé Ìmọ̀ràn Tó Dáa Ó Máa Ṣe Wá Láǹfààní

Tá A Bá Tẹ̀ Lé Ìmọ̀ràn Tó Dáa Ó Máa Ṣe Wá Láǹfààní

Rèhóbóámù dojú kọ ipò tó gba pé kó ṣèpinnu (2Kr 10:1-4; w18.06 13 ¶3)

Rèhóbóámù ní káwọn míì gba òun nímọ̀ràn (2Kr 10:6-11; w01 9/1 28-29)

Rèhóbóámù kọ ìmọ̀ràn tó dáa tí wọ́n fún un, ìyẹn sì mú kí ìyà jẹ òun àti àwọn èèyàn náà (2Kr 10:12-16; it-2 768 ¶1)

Àwọn àgbàlagbà tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn tí wọ́n sì ní ìrírí máa ń mọ ibi tó ṣeé ṣe kí ọ̀rọ̀ kan já sí.​—Job 12:12.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn wo nínú ìjọ ló lè fún mi ní ìmọ̀ràn tó dáa?’