Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ìmọ̀ràn Onífẹ̀ẹ́ Tí Bàbá Kan Fún Ọmọ Ẹ̀

Ìmọ̀ràn Onífẹ̀ẹ́ Tí Bàbá Kan Fún Ọmọ Ẹ̀

Sapá kó o lè mọ Jèhófà (1Kr 28:9; w05 2/15 19 ¶9)

Fi gbogbo ọkàn rẹ sin Jèhófà (1Kr 28:9; w12 4/15 16 ¶13)

Má bẹ̀rù, Jèhófà ni kó o gbẹ́kẹ̀ lé (1Kr 28:20; w17.09 32 ¶20-21)

Ọba Dáfídì tó ti darúgbó fún Sólómọ́nì ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ ọ̀dọ́ tí ò sì nírìírí nímọ̀ràn kó tó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ tẹ́ńpìlì tó jẹ́ iṣẹ́ tó ṣe pàtàkì. Kí nìdí tí ìmọ̀ràn tó fún un yìí fi wúlò fún gbogbo wa, pàápàá àwọn Kristẹni tó jẹ́ ọ̀dọ́?