March 11-17
SÁÀMÙ 18
Orin 148 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. “Jèhófà Ni . . . Ẹni Tó Ń Gbà Mí Sílẹ̀”
(10 min.)
Jèhófà ni àpáta gàǹgà, odi ààbò àti apata wa (Sm 18:1, 2; w09 5/1 14 ¶3-4)
Jèhófà máa ń gbọ́ tá a bá ké pè é fún ìrànlọ́wọ́ (Sm 18:6; it-2 1161 ¶7)
Jèhófà máa ń ràn wá lọ́wọ́ (Sm 18:16, 17; w22.04 3 ¶1)
Jèhófà lè pinnu láti yanjú àwọn ìṣòro kan tá a ní bó ṣe ṣe fún Dáfídì. Àmọ́ lọ́pọ̀ ìgbà, ó máa ń “ṣe ọ̀nà àbáyọ” ní ti pé ó máa ń fún wa lóhun tá a nílò ká lè fara da ìṣòro wa, ká má sì bọ́hùn.—1Kọ 10:13.
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Sm 18:10—Kí nìdí tí onísáàmù náà fi sọ pé Jèhófà gun kérúbù? (it-1 432 ¶2)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Sm 18:20-39 (th ẹ̀kọ́ 10)
4. Jẹ́ Onínúure—Ohun Tí Jésù Ṣe
(7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 1-2.
5. Jẹ́ Onínúure—Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jésù
(8 min.) Ìjíròrò tó dá lórí lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 3-5 àti “Tún Wo.”
Orin 60
6. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(5 min.)
7. Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March
(10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà.
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 7 ¶1-8, àpótí ojú ìwé 53