March 25-31
SÁÀMÙ 22
Orin 19 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Bíbélì Sọ Tẹ́lẹ̀ Nípa Ohun Táá Ṣẹlẹ̀ Nígbà Ikú Jésù
(10 min.)
Ó máa dà bíi pé Ọlọ́run ti kọ Jésù sílẹ̀ (Sm 22:1; w11 8/15 15 ¶16)
Wọ́n á fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́, wọ́n á sì sọ̀rọ̀ àbùkù sí i (Sm 22:7, 8; w11 8/15 15 ¶13)
Wọ́n á ṣẹ́ kèké lórí aṣọ Jésù (Sm 22:18; w11 8/15 15 ¶14; wo àwòrán iwájú ìwé)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Sm 22:22—Àwọn ọ̀nà méjì wo la lè gbà ṣe bíi ti onísáàmù náà lónìí? (w06 11/1 29 ¶7; w03 9/1 20 ¶1)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Sm 22:1-19 (th ẹ̀kọ́ 2)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. (lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 4)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Pa dà lọ sọ́dọ̀ ẹnì kan tó o pè, tó sì wá sí Ìrántí Ikú Kristi. (lmd ẹ̀kọ́ 4 kókó 3)
6. Àsọyé
(5 min.) w20.07 12-13 ¶14-17—Àkòrí: Bí Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Ṣe Ń Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wa Túbọ̀ Lágbára. (th ẹ̀kọ́ 20)
Orin 95
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 7 ¶14-18, àwọn àpótí ojú ìwé 57-58