April 7-13
ÒWE 8
Orin 89 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
1. Fetí sí Ọgbọ́n Jésù
(10 min.)
Jèhófà dá Jésù “gẹ́gẹ́ bí ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀nà rẹ̀,” òun sì ni ọgbọ́n Ọlọ́run (Owe 8:1, 4, 22; cf 131 ¶7)
Torí pé ọ̀pọ̀ ọdún ni Jésù fi wà pẹ̀lú Bàbá ẹ̀ nígbà tó ń dá àwọn nǹkan, ọgbọ́n rẹ̀ àti ìfẹ́ tó ní sí Bàbá ẹ̀ pọ̀ gan-an (Owe 8:30, 31; cf 131-132 ¶8-9)
A máa jàǹfààní tá a bá ń tẹ́tí sí ọgbọ́n Jésù (Owe 8:32, 35; w09 4/15 31 ¶14)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Owe 8:22-36 (th ẹ̀kọ́ 10)
4. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Ẹni náà sọ pé ó ṣeé ṣe kóun wá sí Ìrántí Ikú Kristi, ó sì béèrè àwọn nǹkan tó máa ṣẹlẹ̀ níbẹ̀. Dáhùn àwọn ìbéèrè ẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)
5. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Ẹnì kan rí ìwé tá a fi ń pe àwọn èèyàn wá sí Ìrántí Ikú Kristi ní ẹnu ọ̀nà ẹ̀, ó sì wá. Kí ẹni náà dáadáa kí ìpàdé tó bẹ̀rẹ̀, kó o sì dáhùn ìbéèrè tó bá ní lẹ́yìn ìpàdé náà. (lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 5)
6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́
(5 min.) Àsọyé. ijwbq àpilẹ̀kọ 160—Àkòrí: Kí Nìdí Tí A Fi Pe Jésù Ní Ọmọ Ọlọ́run? (th ẹ̀kọ́ 1)
Orin 105
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) bt orí 25 ¶1-4, àpótí ojú ìwé 199